Èdè Ainu
Èdè Ainu Èdè kan tí ó dá dúró ní òun nìkan ni èdè yìí. A kò mọ iye ẹni tí ó ń sọ ọ ṣùgbọ́n ètò ìkànìyàn ọdún 1996 so pe márùndínlógún ni wọ́n. Hokkaido, Japan àti ní Sakhalin àti Erékùsù Kuril. Ní ìbẹ̀rẹ̀ sẹ́ńtúrì ogún, púpọ̀ núnú àwọn ohun tí ó se pàtàkì nínú èdè àti àṣa Ainu ni Jepaníìsì ti gba ipò wọn
Ainu | |
---|---|
Ìpínká ìyaoríilẹ̀: | Hokkaidō; formerly southern and central Sakhalin, the Kuril Islands, and perhaps the tip of the Kamchatka Peninsula and theTōhoku Region of Honshū |
Ìyàsọ́tọ̀: | A primary language family |
Àwọn ìpín-abẹ́: | Sakhalin Ainu Kuril Ainu |
![]() | Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
🔥 Top keywords: Ojúewé Àkọ́kọ́Pàtàkì:SearchOgun Àgbáyé Ẹlẹ́ẹ̀kejìỌ̀rọ̀-Orúkọ (Èdè Yorùbá)Àṣà YorùbáÀsà oge ṣíṣẹ́ ní ilè yorùbáFáwẹ̀lì YorùbáṢàngóWiki HowPàtàkì:ÀwọnÀtúnṣeTuntunÈdè YorùbáEre idarayaWikipedia:Nípa Wiki HowÒgún LákáayéÀṣà Ìsọmọ-lórúkọ nílẹ̀ YorùbáWikipedia:Abẹ́ igiIṣẹ́ Àgbẹ̀Fáìlì:Adeniran Ogunsanya.jpgMọ́remí ÁjàṣoroMediaWikiAkanlo-edeOwe YorubaÒrìṣà EgúngúnÀsà Ìgbéyàwó ní ilè YorùbáÀrokòÀwọn orin ilẹ̀ YorùbáOmiWikipedia:Èbúté ÀwùjọÀwọn Ọba Ilẹ̀ YorùbáDHEewo ninu awon igbagbo YorubaGoogleYẸ̀yà ara ìfọ̀WizkidEBÈbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyí